Ofò ti Oséètura
E ni ibodé yìí, Kò si òsán , kò si òru
Aqui (na terra) é a porta do céu,
pode – se entrar nela de dia ou de noite;
Kò si òtútù, bèéni kò
si ooru
Nela (na porta do céu) não há frio ,
e não há calor
Ohun àsírií kan kò si ní
ibodé yìí
Na porta do céu não há segredo
Ohun gbogbo dúró kedere
Ìmólè Olórun
Todas as coisas serão claras ( na
porta do céu) diante do espírito de Deus
Àyànmó kò gbó oògùn
Que o destino não nos faça usar
remédios
Akúnlèyàn òun ní
àdáyébá
Que as pessoas adorem de joelhos as
coisas do céu, para que venha coisas boas para terra
Àdàyébá ní àdàyé sé
Que todos encontrem sempre coisas
boas na terra.
Àsé o!!
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
Elémèrè déhìn mi ó;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn mi;
Àbíkú déhìn mi o;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
.......................................
Òséètura !!!!!!!
O ri ìsè àwon ará iye bìí, bi n
wón ti n síse si,
Kiri ká léni ti ti lá tòrun
a ba wà iyè ti n wón ki n padà léhìn eni,
Omo àràiyé Lee, bi àiyé bà’sé ìkà tán n wón
ní olóre won ki ngbe etí ilé;
Mo ní oke gárán , Òrúnmìlà ní ó ké gárán
Mo ní eètìrì, èé a ti se, ki ní
ké gárán, n wón ni Omo Olúifè Yi lóde,
Bi omo Olúifè Yi
bádé, e lo tójú okúnrin weleiye jántere,
lórúko Agbo Ògún;
Ki o lo pádè àwon eleye,
olójú kokoro, olójú kakaka, ti n wón síse ibi sini ti n
wón n fi Omo lómo dájo, n wón gbé dudu Le fúnfún lowó;
Ògún ló ibè n wón ó Le mú
won. Nwón ló pè kògbélé níle kò sé ran ti nsí wájú elebo
, ti gbèhìn elébo ti n elébo ni ebó
si àyé òrún gúle gúle lorúko Òséètura .
O ló pàdé àwon èléye
,Ó ní oríkan lekún ní ti n fí ségun n gba eranko orí kan
lejò ní ti n fí ségun n gba n fí gbenu;
Oríkan làsé ní n fí ségun
n gba eye ,Òséètura ó ségun gbogbo won,
gbogbo wa pata ka ségun òta àwa ni ki a réhín òta ,
ki a réhìn odìì; gbogbo wa pata àtépé ni esè
n’ te ònòn ;
Àba téni jé déhìn léhìn
mi ó
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn mi;
Àbínu eni déhìn mi ó ;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
Elémèrè déhìn mi ó;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
Àbíkú déhìn mi o;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi.....
Àsé ......
Ouça também a orin (música) deste ijala pelo link abaixo
https://plus.google.com/u/0/109818862360638616292/videos
Ouça também a orin (música) deste ijala pelo link abaixo
https://plus.google.com/u/0/109818862360638616292/videos