Mo jùbá awo Orùnmilá
Iwo ni iko Olodùmaré
Iwo ni Olupilese awo odu Ifá
Iwo ni Ifá
Iwo ni Oluwa awo Igba Owo eyo
Iwo ni ohun idarisi
Iwo ni Oluwa asiri iwa
Iwo ni òrìsà julo loye.
Iwo ni iko Olodùmaré
Iwo ni Olupilese awo odu Ifá
Iwo ni Ifá
Iwo ni Oluwa awo Igba Owo eyo
Iwo ni ohun idarisi
Iwo ni Oluwa asiri iwa
Iwo ni òrìsà julo loye.
Nenhum comentário:
Postar um comentário