Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
Elémèrè déhìn mi ó;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
Àbíkú déhìn mi o;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
.......................................
Òséètura !!!!!!!
O ri ìsè àwon ará iye bìí, bi
n wón ti n síse si,
Kiri ká léni ti ti lá tòrun
a ba wà iyè ti n wón ki n padà léhìn eni,
Omo àràiyé Lee, bi àiyé bà’sé ìkà tán n wón
ní olóre won ki ngbe etí ilé;
Mo ní oke gárán , Òrúnmìlà ní ó ké gárán
Mo ní eètìrì, èé a ti se, ki
ní ké gárán, n wón ni Omo Olúifè Yi lóde,
Bi omo Olúifè Yi
bádé, e lo tójú okúnrin weleiye jántere,
lórúko Agbo Ògún;
Ki o lo pádè àwon eleye,
olójú kokoro, olójú kakaka, ti n wón síse ibi sini ti n
wón n fi Omo lómo dájo, n wón gbé dudu Le fúnfún lowó;
Ògún ló ibè n wón ó Le
mú won. Nwón ló pè kògbélé níle kò sé ran ti nsí wájú elebo
, ti gbèhìn elébo ti n elébo ni ebó
si àyé òrún gúle gúle lorúko Òséètura .
O ló pàdé àwon èléye
,Ó ní oríkan lekún ní ti n fí ségun n gba eranko orí kan
lejò ní ti n fí ségun n gba n fí gbenu;
Oríkan làsé ní n fí ségun
n gba eye ,Òséètura ó ségun gbogbo won,
gbogbo wa pata ka ségun òta àwa ni ki a réhín òta ,
ki a réhìn odìì; gbogbo wa pata àtépé ni esè
n’ te ònòn ;
Àba téni jé déhìn léhìn
mi ó
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn mi;
Àbínu eni déhìn mi ó ;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
Elémèrè déhìn mi ó;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi;
Àbíkú déhìn mi o;
Òwòrín sórógbe óó,
Isíkikù péhìnda léhìn
mi.....
Àsé ......
Nenhum comentário:
Postar um comentário